LABELS - FEAR

Do you love grey?

FEAR

Ṣàngó olúkòso wọlu! Ilé pa lọ́lọ́
How scared are you of tomorrow?

Ògún lákāyé fé jẹ́ wé tẹ̀dọ̀, ènìyán pọ̀ rà
Does fear breed in you? How many of its kinds?

Iná l’ójú, iná l’ẹ́nu. Kò ṣe wò, kò ṣe sá fún
When will you be great? Fear sure is rooted in you 

Ẹní bá pa'rọ́ f'ògún, á wẹ̀ l'àgbàrá ẹ̀jẹ́
Stop the lie to yourself, this isn’t your limit

Yèyé ọba bínú, Ó sọ ara rẹ̀ di ọ̀dọ́
Let anger push away that which limits you

Iyemọja nda ìgboro ọ̀sà rú; ọmọ rẹ̀ kan sọnù
Quiet your pursuits, success makes a loud noise

Wọ́n fún èṣù ‘la adin, ibi wọ ìlú
When you feed fear, it eats up your whole being

Ta ló bẹ èṣù l'ọ́wẹ̀? Inú ènìyàn l'ẹgbin
The wicked can smell your fear! Beware!

Èṣù lālu ògiri ókó pa'wọ́ pọ̀ pẹ̀lú Ògún
Fear that grips and cripples man, how laudable are you?

Ta ló mọ ìbẹ̀rù? Ta ló ríi? Ta ló nbọ? Ènìyàn ni.
We give power to what we feel, we feed fear – Fear not!

Ọ̀rẹ́ fi ìbẹ̀rù sílẹ̀. Kò sí ewu l'ode, àfi gìrìrì àparò
Be woke! Wade through your fear and be strong!
lanrewaju Oluwatosin Racheal pen name 'Tosraheal' is an avid reader and a budding young writer, she loves art and likes to dabble in different creative works. 

All rights to this content is reserved, No part of this content may be used or reproduced in any form without the prior written permission of the writer, except in the case of brief quotations embodied in critical reviews and uses permitted by copy right law. For permission requests, email the media team at: content@niwcolony.com. Please click on the subscribe button to receive latest blog updates.

No comments:

Post a Comment

How BIZEdo AGN elects Osagie Elegbe as New Chairman

Edo AGN elects Osagie  Elegbe as new chairman According to Adedayo Odulaja, Edo state chapter of the Actors Guild of Nigeria (AGN)...